Ore ofe Jesu by Tope Alabi
Intro-
Mori ire ayo ibukun,
Mori ogo ayanmon to pe pere.
Ola po ja burata oro agbon igbe,
gbogbo eyi ti ri emi loni won, baba lo fi fun mi,
Oore ofe Jesu×3
Ati anu lon to mileyin
Ore ofe Jesu o,Oore ofe Jesu, Oore ofe Jesu Ati anu lo tomileyin
Ona mi la igi ayi dina ti wo womu womu, dipo akete aisan sekere Ope lo gbe le mi lowo, Moti wi itele ayo mi ku ko I tan oluwa lotun mise, isoji Ope laye gba boluoluwa ti fe funmi niyen (boluwatife funmi niyen o, )
Chorus:
Oore ofe Jesu
(Ayo mi ku opo nle repete)
Oore ofe Jesu
(Ko letan beni)
Ore ofe Jesu
(Oluwa lofunmi se o)
Ore ofe Jesu
(Isoji Ope laye mi gba)
Ore ofe Jesu
(Un o ma gbe kiri ni)
Ore ofe Jesu
(Gbogbo agbaye ni no ti se isoji Ope)
Ore ofe Jesu Ati anu lo tomileyin
Intro
Alayo ni mi o, ore ofe ati anu ,loto wa o ati emi ati ile mi leyin o.
Bi mo ba jade bi mo ba wo le
All ;ire Ire
Bi mo ba sun lale, ti mo ji lowuro o
All ire : Ire
Adawo lemi ko yori si ogo o
All ire : Ire
Oore ofe Jesu christ ati anu ko deyin miii
All ire : Ire
Oro mi ja so pe ni gbogbo ona ni o
All ire : Ire
Bi ti mo ba te a sun rere fun mi
All ire : Ire
Ire ni waju mi ire leyin ire lo nro funmi o
All ire : Ire
Ayo legbe otun legbe osi niwaju leyin mi o
All ire : Ire
Ife oluwa Jesu christ ko lefi mi sile lailai
All ire Ire
Chorus:
(Oore ofe Jesu ni)
Ore ofe Jesu
(On tomileyin)
Ore ofe Jesu
(On ba mi gbe)
Ore ofe Jesu
(On ba mi sun)
Ore ofe Jesu
(Oba mi ji o)
(Gbogbo ibi ti mo ba te)
Ore ofe Jesu
(Mo gba be ni ile ini )
Ore ofe Jesu
(Anu wa mi ri)
Ore ofe Jesu
(Ore ofe sare temi leyin mi)
Ore ofe Jesu
(Olorun lose mi be)
Nitoto ire ati anu ore ofe.
Koma to o leyin, ni gbogbo ojo aye re
Adura ojo pipe
Ogba esi ayo logan amin o.
Alanu ko wa e ri, ko ma se lala lasan
O..o ni ise mu fun ota beni o.. oni teni ti ka laye towa o
Awotelere ati tode yio ma bi ogo fun o ni. Ore ofe ati ife olorun ko ma ko ti wa papo.
Chorus (3*)
Ore ofe Jesu,
Ore ofe Jesu,
(Etewo Audra mo wi o) ore ofe Jesu,
(Oore ofe Jesu Ati anu, ojurere, ati fe Oluwa ko ma tele wa ..... Atanu ..
lon tomileyin
(Iwo lo da afun , awa lo dafun ohun lo da emi fun, ninu re ni mo tin je ti mo tin mu baba lo se be)