Friday, June 21, 2024

Oldschool choir song Isokan Dara

Isokan Dara


 Isokan Dara 3x Ara mi o eloronu si 2x "Ara"

1.eke Ko Lara opoto Inu bibeli nigba toluwa koja nibe Ni selese Sigi, nitoripe okuna lati so ESO toye Ni asiko titi aye kotun le so ESO Miran Mo o, EsO rere Kemi Oso laye mi ESO rere Kemi Oso eso rere.

Baba was Tosi pohun lajara AWA Ni Eka, Eka to ba yapa Kuro Lara ajara irugbin Ina Ni won isokan Sani Jesu nfe, ninu ogba baba leso eso ripe o

Chorus

Gbogbo Eka esowopo ka Jo sise foluwa, sise tokan-tokan bi won Se akiye si e, eje ka Jo sowopo ka Jo gbe ijo wa GA. Sepinu lokan re lati sin takuntakun.

Taken like ewi

Moni tan kekere Kan lori baba ati omo meta kan ti won Ko feran AFI Ko ma Jani, baba tin darugbo ope awon Omo Jo pe awon Omo Jo, omugi meta ti won so opo ofun akobi PE Ko Kan ogbiyanju titi Ko ma ri Se, ekeji gbiyan ju Ko ma ri se, iketa Ko le Se Se, baba Bani ki won tu, ki won se lokan Kan. Loba Di were. Ti ABA sowo Po Ko si besu Se ri wa mu, eje ka so wopo kafi Ife barawa lo, Oluwa yio ran wa lowo.

Chorus

No comments:

Post a Comment