Friday, June 21, 2024

Oldschool choir song Biwo ba gbagbo o

Oldschool choir song 

Biwo ba gbagbo o


 Chorus: Biwo ba gbagbo o o, biwo ba gba Jesu gbo o , Mo ba o yo oju asegun lo. All rept

Biwo ba le gbagbo Iwo yo magbara baba oke soro gbogbo Adi petele, Ogun esu asa, Ogun ese awolelo.

Iji damu aye re o, apalolo.

Ogun iponju ati ya o ninu aye re. Biwo ba gbagbo o, Iwo ti ju asegun lo.

"Nitori"

Bogun aye ngbona Mo girigiri,. Bogun esu Fi o logbologbo. To si tun dabi enipe kosolugbe ja.

Nigba idanwo, nigba isoro, nigba iponju tabi wahala o, gboju re soke kepe olugbala o, awon to wa pelu re ki seniyan, yo Muse o, yio mi leri Se I, Biwo bati gbagbo

Bogun OTA ngbona Mo girigiri, tinu Ni Bini nfi o logbologbo. Tosi tun dabi enipe Ko Sala ba ro. Nigba iji ayen Fe o, ninu irunmi, gbati re dopin o, gboju re soke kepe olugbala o. Awon to wa pelu re ju gbogbo aye lo, ranti Eni to seleri yen ki seniyan yo Muse o yio mu leri Se o biwo bati gbagbo.

No comments:

Post a Comment