Jesu nikan Ni, oluso aguntan rere
Jesu nikan Ni, oluso aguntan rere Labe ojiji re Ni ngo simile.
Oluso alabo olupamo eda gbogbo ngo simile o tori pabo re daju.
Tobati Ni Jesu ati lohun gbogbo.
Eni Toni Jesu, odo laye laye.
Agbe oga o, aso odoloro repete.
ASE logo loju awon eniyan re.
Ninu Jesu layo igbala pipe wa, afun o Ni sinmi, to ba gbe kele. Ore mi Faye re fun Jesu,Kole da jogun iye kale da o lare nikeyin Ojo.
Igbekele olorun ajoji isota olorun, on fiku Pani, onfi ya Jeni. Fabo re sinu Jesu ki rorun le jeti re. Yio dun o ninu amu o dasegun. Agbe oga o, Ibukun re aporepete, ki abo todaju Kole je tire.
All: gbekele diromo gbekele Sato baba lo 2x
Call: fabo re sinu Jesu torohun Labo Tope ye abo eniyan.
All: Asan Ni.
Call: talo sinmi le ore
Resp: Mo sinmile, Mo feyin ti Jesu Labo to daju.
Call: ore sinmile Oluwa o.
All: afun o layo repete.
Call: ore gbokan le Jesu o.
All: agbe oga o laye.
Call: """pelu igbagbo Mo wipe""" Ayo mi tide Ewa ba mi yo moti dalayo oro mi ti jasope.
Mo simile Mo feyin ti Jesu Labo todaju.
No comments:
Post a Comment