Oju elese Kole ri ogo re
Chorus
Oju elese Kole ri ogo re, oju elese Kole ri ogo baba 2x
1. Kama ri 2x iwa eri, agbere pansaga irede Oru sohun lo po loro re
Chorus.
2. Kamari2x riba nko, oju kokoro, abetele eh ah sohun lo Po loro re
Chorus
3. Kamari2x iwa eri, oti mimu, Iro pipa sohun lo Po loro re
Chorus
4. kamari2x Cele nko, kerubu lola, alabela eh ah, agbere esin.
Chorus
5. Kamari2x babalawo to sogun aiku fun o sebo Hun na aku, Oni Segun to Se gbeku de Se bo hun Na a ro run
Chorus
No comments:
Post a Comment