Jeko Wu o baba lati mumi gboro
Chorus
Jeko Wu o baba lati mumi gboro 3x
Tor'eni Oba Fe lo le roju rere gba
1. Ohun gbogbo ti Josefu todawole, dara Dara ni gbogbo ibi ti Josefu de, Lon roju rere gba Koma sohun ti Josephu Se, toluwa Ko bukun re, je Ko wun o, lati mumi gboro baba.
Chorus
Ope titi, ti Anna tin kepe Oluwa, odo dun SA Ni Hanna tinlo si silo, odun Kan ma ni, Hanna roju rere Oluwa. Emi Ni Yi o baba mumi gboro.
Oseleri lati mu Abraham u gboro gidi pelu Omo re bii yanrin Eti Okun ni, Modi leri re mu ninu odun ti baba pelu igbagbo Ojo aye mi yio ma gboro ni
No comments:
Post a Comment