Chorus
Oluwa dide o wa Sa Anu mi, igba ati soju rere simi Ni tooto otide.Oluwa dide o wa Sa Anu mi, igba ati soju rere simi Ni tooto Akiko Naa tide.1. Estero roju rere gba o oda Yaba laafin.Hana roju rere gba o Oromo gbe Jo.Igbati soju rere simi Ni hin o akoko Na tide.2. Josephu roju rere gba o eru pada doba.Maria roju rere gba o obi olugbala araye.Igbati soju rere simi Ni hin o akoko Na tide.Oh Lord arise, have mercy on me, for the time to favour me truly the set time has come 2x.Oluwa Jo wo o jekin roju rere gba Call: li Ona mi gbogbo jekin rere gba o.Resp: Oluwa Jo wo o jekin roju rere gba.Call: lenu Eko mi jekin roju rere gba o.Call: lenu owo mi ..........Call: lenu Ise mi..........Call: Nile atode........Call: Ni odo re baba jekin roju rere gba o.Call: favour no man can resist, is all what I askResp: O Lord my God grant me divine favour.Call: divine favour from a
No comments:
Post a Comment