Friday, June 21, 2024

Oldschool choir song by unknown Biwo ba gbagbo o o

Biwo ba gbagbo o o

 Chorus: Biwo ba gbagbo o o, biwo ba gba Jesu gbo o , Mo ba o yo oju asegun lo. All rept

Biwo ba le gbagbo Iwo yo magbara baba oke soro gbogbo Adi petele, Ogun esu asa, Ogun ese awolelo.

Iji damu aye re o, apalolo.

Ogun iponju ati ya o ninu aye re. Biwo ba gbagbo o, Iwo ti ju asegun lo.

"Nitori"

Bogun aye ngbona Mo girigiri,. Bogun esu Fi o logbologbo. To si tun dabi enipe kosolugbe ja.

Nigba idanwo, nigba isoro, nigba iponju tabi wahala o, gboju re soke kepe olugbala o, awon to wa pelu re ki seniyan, yo Muse o, yio mi leri Se I, Biwo bati gbagbo

Chorus: Biwo ba gbagbo o o, biwo ba gba Jesu gbo o , Mo ba o yo oju asegun lo. All rept

Bogun OTA ngbona Mo girigiri, tinu Ni Bini nfi o logbologbo.Tosi tun dabi enipe Ko Sala ba ro.

 Nigba iji Fe o, ninu irunmi , gboju re soke kepe olugbala o. Awon to wa pelu re ju gbogbo aye lo, ranti Eni to seleri yen ki seniyan yo Muse o yio mu leri Se o biwo bati gbagbo.

Interlude; sunmo Lorun o ore kole sun mo o, oferan

yo Muse o yio mu leri Se o biwo bati gbagbo.

Aduro doluwa ki ma jogun ofo

yo Muse o yio mu leri Se o biwo bati gbagbo.

Sati gbagbo patapata ninu Jesu oba

yo Muse o yio mu leri Se o biwo bati gbagbo.

SunmOlorun tokantokan di gbagbo re mu shinshin

yo Muse o yio mu leri Se o biwo bati gbagbo.

No comments:

Post a Comment