Ara onigbagbo
Ejeka bayin Soro
Oro didu didun to ni ye lori
Oro igbala to ti nu bibeli jade wa o
Teti resi Le ki ogbo
Ohun ti iwe mimo so
Oro idile to jeri rere lafiwe idile onigbagbo, idile ti afi ipin le sole sori apata ti Jesu christ, ti a si fi bibeli se ipinle ipinle rere gege bi idile idile to je eri rere idile alayo loje
Eyin ara mi ninu idile Ejeki awa ninu isokan kan gba emimimo olorun laye lati ma dari Ohun gbogbo ,ki a si fi bibeli se ipinle, ipinle rere gege bi idile
Ki ako omo wa loro olorun ,Ka ta ke te sohun to jomo ibi
Idile ton jeri rere idile alayo loje
(....Interlude....God give us Christian home)
Solo olewu o olewu
All olewu o olewu
Solo iwa abikita gege bi idile
All olewu o olewu
Solo oju ise wa gege bi idile
All ani lati see
Solo kaye ma Teri ba fun oko
All ase Eludunmare loje
Solo ko ko ma fi fe baya re lo
All ase Eledunmare loje
Solo idile to yapa olewu pupo
All oleso awon omo Di omo garawa
Solo Eyin obi ko moloro olorun ke ba leni idile alayo pipe
No comments:
Post a Comment