Chorus: Iwo ni mo wa wa oluwa, iwo ni mo wa wa o eni eniyan kin wa so do re kolo le lo fo wa bami pade o baba
1.Ohun gbogbo ni igba wa fun o, igba mi ma re oluwa mo ni lati ri o, beti
se Hannah pade ni shilo lojo won ni je ki igba ayo mi ko de oooo oluwa
(Iwo ni mo wa wa o baba)
2.Oluwa ran mi nise hallelujah gboju soke wo Jesu, wo ko ye,
Wo Jesu arakunrin, won Jesu iwo yio si ri ye,ako sinu oro re, hallelujah gboju soke wo Jesu wa ye
Lati oni lo ko ni nira fun mi ko ni ni ra fun gbogbo wa
All. Ati je ati mu ati se ukan re ati losi bi giga ko ni ni ran fun mi
Oke oke la o ma lo
All. oke oke la o ma lo
Loruko Jesu a ni re le mo ooo
Airiwo ayo la o ma Gbo oooo
All. Airi wo ayo ni ile waaaa
No comments:
Post a Comment