Mo ti d'asegun ninu Jesu Oba
Eyin omo igbala, e ka Hallelujah…..
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Eni t’oba jagun to segun o lo n gbade
Eni t’oba jagun to segun o, lo n gbade
Iye oh (4x) Iye
(Moti d’asegun)
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
(Eni t’oba jagun oh)
Eni t’oba jagun to segun o lo n gbade
Eni t’oba jagun to segun o, lo n gbade
Iye oh (4x) Iye
Halle- Hallelujah, Jesu jagun o segun
Hallelujah a ti f’oruko titun pe mi
(Yes sir)
E yi ti enu Oluwa ti d’aruko
Lati je ade ogo o lowo Olorun
A t’ade Wura oh oh oh lowo baba mi
A ki yio pe wa ni Ikosile Mo
A ki yio pe wa ni ahoro Mo oh
Sugbon a o pe wa ni Hepzibah
Ati ile wa ah ah ah ah ni Beulah
Nitori Oluwa jagun o segun a ti ri iye
(Mo ti d’asegun)
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Eni t’oba jagun to segun o lo n gbade
Eni t’oba jagun to segun o, lo n gbade
Iye oh (4x) Iye
E ho iho ayo, e ho oh Isegun
E hoooooo e ho oh isegun
Awa t’ati f’ayo fami jade ninu kanga igbala
Awa t’ati f’ayo fami jade ninu iwosan
Ire mi de eh oh ire ayo
Ayo mi de oh oh oh oh oh ayo ayo
Awa t’ati wosan e fo f’ayo
E so f’elese pe oh igbala re de
Jesu ti ra wa pada, a ti d’asegun a ti ri iye
(Moti d’asegun)
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Eni t’oba jagun to segun o lo n gbade
Eni t’oba jagun to segun o, lo n gbade
Iye oh (4x) Iye
Ija d’opin Ogun si tan
(Say)
Olugbala jagun molu
(Ooooorin ayo o)
Orin ayo la o m’ako
(Hallelujah oh oh…..)
Halle- lujah
Ota nta canopy
O fe se le ya mi
Kel’ere won to bere
Baba dana sun won
(O nta canopy)
Ota nta canopy
( O fe se party eleya ara won)
O fe se le ya mi
(Ye Mo ni jesu loluwa)
Kel’ere won to bere
(Emi mimo oh oh oh)
Baba dana sun won
Jesu, Jesu, Jesu, Jesu oh
(Jesu oh)
Arabaribiti eledumare oh
(Jesu oh)
A soro kolu bi ogiri gbigbe
(Jesu oh)
E ba mi pe, e ba mi pe baba yi o
(Jesu oh)
E ba mi pe, e ba mi pe kabiyesi oh
(Jesu oh)
Jesu oh, olori Ogun o
(Jesu oh)
Kabiyesi oh, asoro kolu
(Jesu oh)
Jesu oh, e pe loruko
(Jesu oh)
Oruko t’ape ni gba isoro to n je wa……
More Lyrics from Kay Wonder Songs
Similar Songs
Eyin omo igbala, e ka Hallelujah…..
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Eni t’oba jagun to segun o lo n gbade
Eni t’oba jagun to segun o, lo n gbade
Iye oh (4x) Iye
(Moti d’asegun)
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
(Eni t’oba jagun oh)
Eni t’oba jagun to segun o lo n gbade
Eni t’oba jagun to segun o, lo n gbade
Iye oh (4x) Iye
Halle- Hallelujah, Jesu jagun o segun
Hallelujah a ti f’oruko titun pe mi
(Yes sir)
E yi ti enu Oluwa ti d’aruko
Lati je ade ogo o lowo Olorun
A t’ade Wura oh oh oh lowo baba mi
A ki yio pe wa ni Ikosile Mo
A ki yio pe wa ni ahoro Mo oh
Sugbon a o pe wa ni Hepzibah
Ati ile wa ah ah ah ah ni Beulah
Nitori Oluwa jagun o segun a ti ri iye
(Mo ti d’asegun)
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Eni t’oba jagun to segun o lo n gbade
Eni t’oba jagun to segun o, lo n gbade
Iye oh (4x) Iye
E ho iho ayo, e ho oh Isegun
E hoooooo e ho oh isegun
Awa t’ati f’ayo fami jade ninu kanga igbala
Awa t’ati f’ayo fami jade ninu iwosan
Ire mi de eh oh ire ayo
Ayo mi de oh oh oh oh oh ayo ayo
Awa t’ati wosan e fo f’ayo
E so f’elese pe oh igbala re de
Jesu ti ra wa pada, a ti d’asegun a ti ri iye
(Moti d’asegun)
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Mo ti d’asegun ninu Jesu Oba
Eni t’oba jagun to segun o lo n gbade
Eni t’oba jagun to segun o, lo n gbade
Iye oh (4x) Iye
Ija d’opin Ogun si tan
(Say)
Olugbala jagun molu
(Ooooorin ayo o)
Orin ayo la o m’ako
MOTi dasegun o
I am pressing on
(Hallelujah oh oh…..)
Halle- lujah
Ota nta canopy
O fe se le ya mi
Kel’ere won to bere
Baba dana sun won
(O nta canopy)
Ota nta canopy
( O fe se party eleya ara won)
O fe se le ya mi
(Ye Mo ni jesu loluwa)
Kel’ere won to bere
(Emi mimo oh oh oh)
Baba dana sun won
Jesu, Jesu, Jesu, Jesu oh
(Jesu oh)
Arabaribiti eledumare oh
(Jesu oh)
A soro kolu bi ogiri gbigbe
(Jesu oh)
E ba mi pe, e ba mi pe baba yi o
(Jesu oh)
E ba mi pe, e ba mi pe kabiyesi oh
(Jesu oh)
Jesu oh, olori Ogun o
(Jesu oh)
Kabiyesi oh, asoro kolu
(Jesu oh)
Jesu oh, e pe loruko
(Jesu oh)
Oruko t’ape ni gba isoro to n je wa……