Friday, June 21, 2024

Mike David - Jeti Jesu Lai (Ki Oka Atara mi) lyrics

 Mike David - Jeti Jesu Lai (Ki Okan Atara mi)


Gbati Jesu bade, y'o waba igbagbo laye

(When Jesus shall come, will HE find faith on earth?)

Opo igbagbo, loma ti di igbagbe

(Many have abandoned their faith)

Talaba toka si o, bi omo, Olorun

(Who else can be identified as God's?)

Ti ok ti faso, Aala won, yi eri

(Whose garment isn't yet stained)


BRIDGE

Eyi pada Isreli, apeyinda

(Come back home, lost Israelites)

Jesu nbo, botilo, koma nip emo

(Jesus will return soon just as HE left for heaven)


CHORUS

Ki okan, atara mi, je ti Jesu lai

(That my soul and body, be Christ's alone)


Ewo awon eyan mimo, tiwonto ona aye

(See the saints, now walking wordily)

Opo loko eru, won ko mo Olorun won mo

(Many enslaved, that they have forgotten their God)

Orun si nsofo fun awon mo apeyinda

(Heaven now mourns over backsliders)

Sare pada wale, oni lojo Igbala re

(Come back home, todays is salvation day)


BRIDGE

Eyi pada Isreli, apeyinda

(Come back home, lost Israelites)

Jesu nbo, botilo, koma nip emo

(Jesus will return soon just as HE left for heaven)


CHORUS

Ki okan, atara mi, je ti Jesu lai

(That my soul and body, be Christ's alone)

Oluwa dide o wa Sa Anu mi

 Chorus

Oluwa dide o wa Sa Anu mi, igba ati soju rere simi Ni tooto otide.Oluwa dide o wa Sa Anu mi, igba ati soju rere simi Ni tooto Akiko Naa tide.1. Estero roju rere gba o oda Yaba laafin.Hana roju rere gba o Oromo gbe Jo.Igbati soju rere simi Ni hin o akoko Na tide.2. Josephu roju rere gba o eru pada doba.Maria roju rere gba o obi olugbala araye.Igbati soju rere simi Ni hin o akoko Na tide.Oh Lord arise, have mercy on me, for the time to favour me truly the set time has come 2x.Oluwa Jo wo o jekin roju rere gba Call: li Ona mi gbogbo jekin rere gba o.Resp: Oluwa Jo wo o jekin roju rere gba.Call: lenu Eko mi jekin roju rere gba o.Call: lenu owo mi ..........Call: lenu Ise mi..........Call: Nile atode........Call: Ni odo re baba jekin roju rere gba o.Call: favour no man can resist, is all what I askResp: O Lord my God grant me divine favour.Call: divine favour from a

Jesu nikan Ni, oluso aguntan rere

Jesu nikan Ni, oluso aguntan rere


 Jesu nikan Ni, oluso aguntan rere Labe ojiji re Ni ngo simile.

Oluso alabo olupamo eda gbogbo ngo simile o tori pabo re daju.

Tobati Ni Jesu ati lohun gbogbo.

Eni Toni Jesu, odo laye laye.

Agbe oga o, aso odoloro repete.

ASE logo loju awon eniyan re.

Ninu Jesu layo igbala pipe wa, afun o Ni sinmi, to ba gbe kele. Ore mi Faye re fun Jesu,Kole da jogun iye kale da o lare nikeyin Ojo.

Igbekele olorun ajoji isota olorun, on fiku Pani, onfi ya Jeni. Fabo re sinu Jesu ki rorun le jeti re. Yio dun o ninu amu o dasegun. Agbe oga o, Ibukun re aporepete, ki abo todaju Kole je tire.

All: gbekele diromo gbekele Sato baba lo 2x

Call: fabo re sinu Jesu torohun Labo Tope ye abo eniyan.

All: Asan Ni.

Call: talo sinmi le ore

Resp: Mo sinmile, Mo feyin ti Jesu Labo to daju.

Call: ore sinmile Oluwa o.

All: afun o layo repete.

Call: ore gbokan le Jesu o.

All: agbe oga o laye.

Call: """pelu igbagbo Mo wipe""" Ayo mi tide Ewa ba mi yo moti dalayo oro mi ti jasope.

Mo simile Mo feyin ti Jesu Labo todaju.

Oldschool choir song Biwo ba gbagbo o

Oldschool choir song 

Biwo ba gbagbo o


 Chorus: Biwo ba gbagbo o o, biwo ba gba Jesu gbo o , Mo ba o yo oju asegun lo. All rept

Biwo ba le gbagbo Iwo yo magbara baba oke soro gbogbo Adi petele, Ogun esu asa, Ogun ese awolelo.

Iji damu aye re o, apalolo.

Ogun iponju ati ya o ninu aye re. Biwo ba gbagbo o, Iwo ti ju asegun lo.

"Nitori"

Bogun aye ngbona Mo girigiri,. Bogun esu Fi o logbologbo. To si tun dabi enipe kosolugbe ja.

Nigba idanwo, nigba isoro, nigba iponju tabi wahala o, gboju re soke kepe olugbala o, awon to wa pelu re ki seniyan, yo Muse o, yio mi leri Se I, Biwo bati gbagbo

Bogun OTA ngbona Mo girigiri, tinu Ni Bini nfi o logbologbo. Tosi tun dabi enipe Ko Sala ba ro. Nigba iji ayen Fe o, ninu irunmi, gbati re dopin o, gboju re soke kepe olugbala o. Awon to wa pelu re ju gbogbo aye lo, ranti Eni to seleri yen ki seniyan yo Muse o yio mu leri Se o biwo bati gbagbo.

Oldschool choir song Kigbe faraye mase sinmi

 Kigbe faraye mase sinmi


1. Kigbe faraye mase sinmi, wasu fawon ti Ko gagbo, mase je kelese Ko Ku o, Lai Mo Eni Jesu nse. 2x

Chorus: Toba Fe ole teti, bosi Fe o, ole ma gba, Iwo agbere lowo baba o, Ebi elese koni le Kan o o, ogo asi je tire lojo idajo.

2. Kigbe Ise gidi ni, soro Jesu fun keferi mase je kelese o Sako, Lai Mo Eni Jesu nse

Chorus

3. kigbe faraye mase Simi wasu fawon ti Ko gbagbo .......

Chorus

4. kigbe faraye mase sinmi, Fife Jesu Kristi Han won, mase je kelese Ko Sako Lai Mo ba ologo meta.

Chorus

Oldschool choir song Oju elese Kole ri ogo re


Oju elese Kole ri ogo re

Chorus

Oju elese Kole ri ogo re, oju elese Kole ri ogo baba 2x

1. Kama ri 2x iwa eri, agbere pansaga irede Oru sohun lo po loro re

Chorus.

2. Kamari2x riba nko, oju kokoro, abetele eh ah sohun lo Po loro re

Chorus

3. Kamari2x iwa eri, oti mimu, Iro pipa sohun lo Po loro re 

Chorus

4. kamari2x Cele nko, kerubu lola, alabela eh ah, agbere esin.

Chorus

5. Kamari2x babalawo to sogun aiku fun o sebo Hun na aku, Oni Segun to Se gbeku de Se bo hun Na a ro run

Chorus

Jeko Wu o baba lati mumi gboro by unknown

 Jeko Wu o baba lati mumi gboro 


Chorus

Jeko Wu o baba lati mumi gboro 3x

Tor'eni Oba Fe lo le roju rere gba

1. Ohun gbogbo ti Josefu todawole, dara Dara ni gbogbo ibi ti Josefu de, Lon roju rere gba Koma sohun ti Josephu Se, toluwa Ko bukun re, je Ko wun o, lati mumi gboro baba.

Chorus

Ope titi, ti Anna tin kepe Oluwa, odo dun SA Ni Hanna tinlo si silo, odun Kan ma ni, Hanna roju rere Oluwa. Emi Ni Yi o baba mumi gboro.

Oseleri lati mu Abraham u gboro gidi pelu Omo re bii yanrin Eti Okun ni, Modi leri re mu ninu odun ti baba pelu igbagbo Ojo aye mi yio ma gboro ni